Gẹn 38:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li o bère lọwọ awọn ọkunrin ibẹ̀ na pe, Nibo ni panṣaga nì ngbé, ti o wà ni Enaimu li ẹba ọ̀na? Nwọn si wipe, Panṣaga kan kò sí nihin.

Gẹn 38

Gẹn 38:12-30