Gẹn 37:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si tun lá alá miran, o si rọ́ ọ fun awọn arakunrin rẹ̀, o wipe, Sa wò o, mo tun lá alá kan si i; si wò o, õrùn, ati oṣupa, ati irawọ mọkanla nforibalẹ fun mi.

Gẹn 37

Gẹn 37:6-12