Gẹn 37:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sa wò o, awa nyí ití li oko, si wò o, ití mi dide, o si duro ṣanṣan; si wò o, ití ti nyin dide duro yiká, nwọn si ntẹriba fun ití mi.

Gẹn 37

Gẹn 37:5-13