Gẹn 37:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn arakunrin rẹ̀ ri pe baba wọn fẹ́ ẹ jù gbogbo awọn arakunrin rẹ̀ lọ, nwọn korira rẹ̀, nwọn kò si le sọ̀rọ si i li alafia.

Gẹn 37

Gẹn 37:1-7