Gẹn 37:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si mú ẹ̀wu Josefu, nwọn si pa ọmọ ewurẹ kan, nwọn si rì ẹ̀wu na sinu ẹ̀jẹ na.

Gẹn 37

Gẹn 37:27-34