Gẹn 37:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọkunrin na si wipe, Nwọn ti lọ kuro nihin; nitori mo gbọ́, nwọn nwipe, ẹ jẹ ki a lọ si Dotani. Josefu si lepa awọn arakunrin rẹ̀, o si ri wọn ni Dotani.

Gẹn 37

Gẹn 37:7-24