Gẹn 36:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wọnyi si li awọn ọmọ Aholibama, ọmọbinrin Ana, ọmọbinrin Sibeoni, aya Esau: on si bí Jeuṣi fun Esau, ati Jaalamu, ati Kora.

Gẹn 36

Gẹn 36:7-24