Gẹn 36:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. WỌNYI si ni iran Esau, ẹniti iṣe Edomu.

2. Esau fẹ́ awọn aya rẹ̀ ninu awọn ọmọbinrin Kenaani; Ada, ọmọbinrin Eloni, enia Hitti, ati Aholibama, ọmọbinrin Ana, ọmọbinrin Sibeoni, ara Hiffi;

Gẹn 36