Gẹn 35:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si tẹ́ pẹpẹ kan nibẹ̀, o si sọ orukọ ibẹ̀ na ni El-bet-el: nitori pe nibẹ̀ li Ọlọrun tọ̀ ọ wá, nigbati o sá kuro niwaju arakunrin rẹ̀.

Gẹn 35

Gẹn 35:1-10