Gẹn 35:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si fi gbogbo àjeji oriṣa ti o wà lọwọ wọn fun Jakobu, ati gbogbo oruka eti ti o wà li eti wọn: Jakobu si pa wọn mọ́ li abẹ igi oaku ti o wà leti Ṣekemu.

Gẹn 35

Gẹn 35:2-7