Gẹn 35:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun si wi fun u pe, Jakobu li orukọ rẹ: a ki yio pè orukọ rẹ ni Jakobu mọ́, bikoṣe Israeli li orukọ rẹ yio ma jẹ́: o si sọ orukọ rẹ̀ ni Israeli.

Gẹn 35

Gẹn 35:4-11