Gẹn 34:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Hamori si bá wọn sọ̀rọ pe, Ọkàn Ṣekemu, ọmọ mi, nfẹ́ ọmọbinrin nyin; emi bẹ̀ nyin, ẹ fi i fun u li aya.

Gẹn 34

Gẹn 34:5-16