Gẹn 34:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ọrọ̀ wọn gbogbo, ati gbogbo ọmọ wọn wẹ́rẹ, ati aya wọn ni nwọn dì ni igbekun, nwọn si kó ohun gbogbo ti o wà ninu ile lọ.

Gẹn 34

Gẹn 34:23-30