Gẹn 34:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn ti njade li ẹnubode ilu wọn si fetisi ti Hamori ati ti Ṣekemu ọmọ rẹ̀; a si kọ gbogbo awọn ọkunrin ni ilà, gbogbo ẹniti o nti ẹnubode wọn jade.

Gẹn 34

Gẹn 34:23-30