Gẹn 34:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ bère ana lọwọ mi ati ẹ̀bun bi o ti wù ki o pọ̀ to, emi o si fi fun nyin gẹgẹ bi ẹnyin o ti kà fun mi: ṣugbọn ẹ fun mi li omidan na li aya.

Gẹn 34

Gẹn 34:10-13