Gẹn 33:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati Lea pẹlu ti on ti awọn ọmọ rẹ̀ sunmọ ọdọ rẹ̀, nwọn si tẹriba: nikẹhin ni Josefu ati Rakeli si sunmọ ọdọ rẹ̀, nwọn si tẹriba.

Gẹn 33

Gẹn 33:4-8