Gẹn 33:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Esau si sure lati pade rẹ̀, o si gbá a mú, o si rọmọ́ ọ li ọrùn, o si fi ẹnu kò o li ẹnu: nwọn si sọkun.

Gẹn 33

Gẹn 33:1-11