Gẹn 33:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Esau si wipe, Njẹ ki emi ki o fi enia diẹ silẹ pẹlu rẹ ninu awọn enia ti o pẹlu mi. On si wipe, Nibo li eyini jasi, ki emi ki o sa ri õre-ọfẹ li oju oluwa mi.

Gẹn 33

Gẹn 33:11-20