Gẹn 33:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi bẹ̀ ọ, gbà ẹ̀bun mi ti a mú fun ọ wá; nitori ti Ọlọrun fi ore-ọfẹ ba mi ṣe, ati pe, nitori ti mo ní tó. O si rọ̀ ọ, on si gbà a.

Gẹn 33

Gẹn 33:1-14