Gẹn 32:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si fi aṣẹ fun eyiti o tète ṣaju wipe, Nigbati Esau, arakunrin mi, ba pade rẹ, ti o si bi ọ wipe, Ti tani iwọ? nibo ni iwọ si nrè? ati ti tani wọnyi niwaju rẹ?

Gẹn 32

Gẹn 32:15-21