Gẹn 32:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si sùn nibẹ̀ li alẹ ijọ́ na; o si mú ninu ohun ti o tẹ̀ ẹ li ọwọ li ọrẹ fun Esau, arakunrin rẹ̀;

Gẹn 32

Gẹn 32:4-23