Gẹn 32:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi bẹ̀ ọ, gbà mi lọwọ arakunrin mi, lọwọ Esau: nitori ti mo bẹ̀ru rẹ̀, ki o má ba wá lati kọlù mi, ti iya ti ọmọ.

Gẹn 32

Gẹn 32:8-13