Gẹn 31:52 Yorùbá Bibeli (YCE)

Òkiti yi li ẹri, ọwọ̀n yi li ẹri, pe emi ki yio rekọja òkiti yi sọdọ rẹ; ati pe iwọ ki yio si rekọja òkiti yi ati ọwọ̀n yi sọdọ mi fun ibi.

Gẹn 31

Gẹn 31:48-55