Gẹn 31:44 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ nisisiyi, wá, jẹ ki a bá ara wa dá majẹmu, temi tirẹ; ki o si ṣe ẹrí lãrin temi tirẹ.

Gẹn 31

Gẹn 31:41-53