Gẹn 31:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Inu si bi Jakobu, o si bá Labani sọ̀: Jakobu si dahùn o wi fun Labani pe, Kini irekọja mi? kili ẹ̀ṣẹ mi ti iwọ fi lepa mi wìriwiri bẹ̃?

Gẹn 31

Gẹn 31:34-46