Gẹn 31:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẽṣe ti iwọ fi salọ li aṣíri, ti iwọ si tàn mi jẹ; ti iwọ kò si wi fun mi ki emi ki o le fi ayọ̀ ati orin, ati ìlu, ati dùru, sìn ọ;

Gẹn 31

Gẹn 31:23-28