Gẹn 31:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si mú awọn arakunrin rẹ̀ pẹlu rẹ̀, o si lepa rẹ̀ ni ìrin ijọ́ meje: o si bá a li oke Gileadi.

Gẹn 31

Gẹn 31:19-29