Gẹn 31:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe li akokò ti awọn ẹran yún, mo si gbé oju mi soke, mo si ri li oju-alá, si kiyesi i, awọn obukọ ti o ngùn awọn ẹran jẹ́ oni-tototó, abilà, ati alamì.

Gẹn 31

Gẹn 31:1-12