Gẹn 31:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. O SI gbọ́ ọ̀rọ awọn ọmọ Labani ti nwọn wipe, Jakobu kó nkan gbogbo ti iṣe ti baba wa; ati ninu ohun ti iṣe ti baba wa li o ti ní gbogbo ọrọ̀ yi.

2. Jakobu si wò oju Labani, si kiyesi i, kò ri si i bi ìgba atijọ.

Gẹn 31