Gẹn 30:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Rakeli si wipe, Ijakadi nla ni mo fi bá arabinrin mi ja, emi si dá a: o si sọ orukọ rẹ̀ ni Naftali.

Gẹn 30

Gẹn 30:1-10