Gẹn 30:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NIGBATI Rakeli ri pe on kò bimọ fun Jakobu, Rakeli ṣe ilara arabinrin rẹ̀; o si wi fun Jakobu pe, Fun mi li ọmọ, bikoṣe bẹ̃ emi o kú.

Gẹn 30

Gẹn 30:1-7