Gẹn 3:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li õgùn oju rẹ ni iwọ o ma jẹun, titi iwọ o fi pada si ilẹ; nitori inu rẹ̀ li a ti mu ọ wá, erupẹ sa ni iwọ, iwọ o si pada di erupẹ.

Gẹn 3

Gẹn 3:9-24