Gẹn 3:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si fi ọta sãrin iwọ ati obinrin na, ati sãrin irú-ọmọ rẹ ati irú-ọmọ rẹ̀: on o fọ́ ọ li ori, iwọ o si pa a ni gigĩsẹ.

Gẹn 3

Gẹn 3:12-19