Gẹn 3:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA Ọlọrun si bi obinrin na pe, Ewo ni iwọ ṣe yi? Obinrin na si wipe, Ejò li o tàn mi, mo si jẹ.

Gẹn 3

Gẹn 3:8-18