Gẹn 28:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Esau tọ̀ Iṣmaeli lọ, o si fẹ́ Mahalati ọmọbinrin Iṣmaeli, ọmọ Abrahamu, arabinrin Nebajotu, kún awọn obinrin ti o ni.

Gẹn 28

Gẹn 28:8-13