Gẹn 28:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o si fi ibukún Abrahamu fun ọ, fun iwọ ati fun irú-ọmọ rẹ pẹlu rẹ; ki iwọ ki o le ni ilẹ na ninu eyiti iwọ nṣe atipo, ti Ọlọrun fi fun Abrahamu.

Gẹn 28

Gẹn 28:3-8