Gẹn 28:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Okuta yi, ti mo fi lelẹ ṣe ọwọ̀n ni yio si ṣe ile Ọlọrun: ati ninu ohun gbogbo ti iwọ o fi fun mi, emi o si fi idamẹwa rẹ̀ fun ọ.

Gẹn 28

Gẹn 28:16-22