Gẹn 28:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jakobu si jẹ́ ẹjẹ́ wipe, Bi Ọlọrun ba pẹlu mi, ti o si pa mi mọ́ li ọ̀na yi ti emi ntọ̀, ti o si fun mi li ohun jijẹ, ati aṣọ bibora,

Gẹn 28

Gẹn 28:12-22