Gẹn 28:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹrù si bà a, o si wipe, Ihinyi ti li ẹ̀ru tó! eyi ki iṣe ibi omiran, bikoṣe ile Ọlọrun, eyi si li ẹnubode ọrun.

Gẹn 28

Gẹn 28:9-22