Gẹn 28:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si de ibi kan, o duro nibẹ̀ li oru na, nitori õrùn wọ̀; o si mu ninu okuta ibẹ̀ na, o fi ṣe irọri rẹ̀, o si sùn nibẹ̀ na.

Gẹn 28

Gẹn 28:1-19