Gẹn 27:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lọ nisisiyi sinu agbo-ẹran, ki o si mu ọmọ ewurẹ meji daradara fun mi lati ibẹ̀ wá: emi o si sè wọn li ẹran adidùn fun baba rẹ, bi irú eyiti o fẹ́:

Gẹn 27

Gẹn 27:3-19