Gẹn 27:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mu ẹran-igbẹ́ fun mi wá, ki o si sè ẹran adidùn fun mi, ki emi ki o jẹ, ki emi ki o sure fun ọ niwaju OLUWA ṣaju ikú mi.

Gẹn 27

Gẹn 27:1-15