Gẹn 27:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

Esau si wi fun baba rẹ̀ pe, Ire kanṣoṣo li o ni iwọ baba mi? sure fun mi, ani fun mi pẹlu, baba mi? Esau si gbé ohùn rẹ̀ soke, o sọkun.

Gẹn 27

Gẹn 27:30-42