Gẹn 26:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si tẹ́ pẹpẹ kan nibẹ̀, o si kepè orukọ OLUWA, o si pa agọ́ rẹ̀ nibẹ̀: awọn ọmọ-ọdọ Isaaki si wà kanga kan nibẹ̀.

Gẹn 26

Gẹn 26:15-27