Gẹn 26:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Abimeleki si wipe, Kili eyiti iwọ ṣe si wa yi? Bí ọkan ninu awọn enia bá lọ bá aya rẹ ṣe iṣekuṣe nkọ? iwọ iba si mu ẹ̀ṣẹ wá si ori wa.

Gẹn 26

Gẹn 26:3-17