Gẹn 25:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Jakobu fi àkara ati ìpẹtẹ lentile fun Esau; o si jẹ, o si mu, o si dide, o si ba tirẹ̀ lọ: bayi ni Esau gàn ogún-ibí rẹ̀.

Gẹn 25

Gẹn 25:29-34