Gẹn 25:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Esau si wi fun Jakobu pe, Emi bẹ̀ ọ, fi ìpẹtẹ rẹ pupa nì bọ́ mi; nitori ti o rẹ̀ mi: nitori na li a ṣe npè orukọ rẹ̀ ni Edomu.

Gẹn 25

Gẹn 25:22-31