Gẹn 25:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si tẹ̀dó lati Hafila lọ titi o fi de Ṣuri, ti o wà niwaju Egipti, bi iwọ ti nlọ sìha Assiria: o si kú niwaju awọn arakonrin rẹ̀ gbogbo.

Gẹn 25

Gẹn 25:17-23