Gẹn 25:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn wọnyi li awọn ọmọ Iṣmaeli, iwọnyi si li orukọ wọn, li ori-ori ilu wọn, li ori-ori ile odi wọn; ijoye mejila li orilẹ-ède wọn.

Gẹn 25

Gẹn 25:12-23