Gẹn 25:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọnyi si li orukọ awọn ọmọkunrin Iṣmaeli, nipa orukọ wọn, ni iran idile wọn: akọ́bi Iṣmaeli, Nebajotu; ati Kedari, ati Adbeeli, ati Mibsamu,

Gẹn 25

Gẹn 25:6-21